A bá Ọmọọba Adewale Láoyè tí wọ́n jẹ́ olùṣàkóso Ààfin Ìlù ní Ìlú Ẹdẹ sọ̀rọ̀ nípa bí wọ́n ṣe ń ṣàfihàn àwọn ìlú ọlọ́kan-ò-jọ̀kan láti fi gbé àṣà àti ìṣe Yorùbá lárugẹ.
Wọ́n ṣàlàyé bí Ààfin Ìlù ṣe bẹ̀rẹ̀ àti ipa ribiribi tí ó ti kó nílùú Ẹdẹ láti ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀, wọ́n sì rọ àwọn ọmọ Àyàngalú kí wọ́n má ṣe gbàgbé orírun wọn nípa ìlú lílù nitori iṣẹ́ tó ṣe é mú yangàn ni.
All rights reserved. This material, and other digital content on this website, may not be reproduced, published, broadcast, rewritten or redistributed in whole or in part without prior express written permission from PUNCH.
Contact: [email protected]
Source: Punch · Our Reporters
At a glance
- Topic
- World
- Country
- 🇳🇬 NG
- Publisher language
- EN
- Added to Allnira